No. 321Iwo apata aiyeyaiye Mo fe ki nri oLyrics1Iwo apata ayeraye mo fe ki n ri o Mo fe duro lori eko re ki nle di akoni Wo bi omi aye ti nbo ajara O fe wo ewe re Ran ojo itura ati oro oke Ko gba nasiri la.2Wo bi iji aiye ati oro aiye Ti ko ra won jo Won n bu lu mi lotun losi Baba yara gba mi3Koriko n ro itana n ru ewe L'aipe iye ojo, baba maje kin le se o Titi de opin emi mi4Gbogbo igi rere ti Olorun gbin Lo n so eso rere; Oluwa jeki nle so eso Ti yio mu inu re dun5Oro apata oro oke Sa wo inu omo re fo oro aimo ati oro aye Kuro lodo omo re6Eh o eh o yara bi mi Idamu aiye de - Se iri iwosan lati oke wa Sori Nasareti reAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957ORIN MIMO NI MONDAY 11/2/57Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous320 · Apa mi ro ese mi roNext 322 · Kilohun ti emi yio se ?