No. 323Ogun nlala, lojo OluwaLyrics1Ogun nlala lojo Oluwa Gbati gbogbo oku yo jinde Ogun nlanla lojo na- a2Yara wole oko igbagbo Ki ipe idajo Oluwa to dun Yara ko eko ki iku to de3Ise ko si ninu iboji Nibiti a o fi o pamo si Yara gbagbo ki iku to de4Ko si imo tabi ete Ni isa oku nibiti on re Yara gbagbo l'owuro yi5Arimagedon lojo idajo Ti iponju yio ba gbogbo elese Arinmagedon lojo na o6Gbogbo oku yio jinde Nwon o gba idajo bi ise owo won Arimagedon ogun nlala7Ipin yio wa fun awon oloto Ko si ipin fun awon alaigbagbo Ogun nlanla ArimagedonAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO NI FRIDAYd. d. d. s. m. m. m.d. d: m. f. s. I.s. f. m. r. m. f. s. d. - I. t. r. d. Previous322 · Kilohun ti emi yio se ?Next 324 · Olorun mi mase fetan ba mi lo