No. 324Olorun mi mase fetan ba mi loLyrics1Olorun mi mase fetan ba mi lo B'omo araiye ti nfetan ba ara won lo Bi mo base O dariji mi o, Baba dariji2Nitori re mo ko obi mi sile Mo ko ile ati ona mi sile Bi mo base O dariji mi o, Baba dariji O3Mo jiya pupo fun O o Eleda mi Egan pupo lo ba mi nitori oro re Bi mo base O dariji mi o, Baba dariji O4Aso alore re Ologo Laiye fe fi ilera gba lowo mi Bi mo se O dariji mi o, Baba dariji O5Ranti pasan ainiye ti mo gba Nigbati o ko fi mana Refun mi Bi mo base O dariji mi o, Baba dariji O6Mase gba iran re kuro lowo mi Bo ti gba iran Balamu fun eran Bi mo se O, mase fetan ba mi lo Ma se fetan ba mi lo7Oluwa so etan si Woli Ahabu Nipa aisedede okan won Oluwa mi, Ma se fetan ba mi lo Ma se fetan ba mi lo.About this hymnWritten byProphet MennaryYear1958Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous323 · Ogun nlala, lojo OluwaNext 325 · Gbo o gbo o