No. 334ILE Herrammar ILE HerrammarLyrics1ILE Herrammar ILE Herrammar Nibe lati ngbo orin ogo Oluwa Nile Herrammar Nile Herrammar Nibe lati ngbo orin ogo Oluwa2Awon Angel duro lenu ilekun Won nfon ipe nkorin ogo Oluwa Awon adaba Sainary nra loke Hemmar Nipa orin tawon Angel nko3Awon Ojo merin duro ni igun ile na Awon angeli nfi iye njo korin Nile Herrammar-Nile Herrammar Nibe lohun orin ti njade4Iwo Adaba Sainary, Iwo Alore Sioni Sama korin orun fun mi Korin ogo fun mi, korin imo funmi5Iwo Ile Herrammar to kun fun Ogo Okan mi nfa si o pupo Bi nba ti gbo orin Ogo ati orin aro re O se mi kin ma tun wo aiye mo.6Wo awon alore orun ni ile Herrammar Nwon nfunfun gbo bi egbon owu Wo awon akorin aiye bi ese ti nba won ja Ti o si nmu won fun baibai.7Iwo Alore Herrammar Iwo Alore Sainary Mehermmar Elo Alore Romisionally alau ERI alau Dahosama Sainary Elo Eli Alore.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Monday 6/10/57 Incopason Sainary Glob Mary Hermmar copy P.S.T.C Grow has LadoneMahemmar Sainary Sencity Copain Glob Alore Sainary Previous333 · Ojo aiye to nro lori miNext 335 · Kini se Oluwa mi