No. 335Kini se Oluwa miLyrics1Kini se Oluwa mi Ti apa re ko fi ka mi lilo Kini se Olorun mi Ti apa re ko fi ka mi lilo2Iwo lo da Orun ati Osupa Iwo nikan lo ndari won kiri Kini se to ti nfi mi sile Fun esu ati ese lati to3Gbogbo awon eda orun to da Ipa re nikan lo fi nto won Kini se ti o ko fi lo mi Bi o ti nlo awon Angeli mimo.4O ran mi wa aiye lati sin O Imole to fun mi ko to mi Ogo aiye si nfe pa imole na Fi ogo orun wo mi5Ase re ni ojo ntele Ase re ni ojo ntele Pase lilo fun mi ki ntele Maje ki ngboro aiye mo6Gbogbo eda orun to da lo nlo Kini se to ti ko mi sile Lo mi bi awon Angeli ti ki ndese Mo se ijewo pe emi yio sin o7Fi oju owo ina re wo mi Ti yio ba ese jagun segun ese Fi oju ainu adaba re wo mi Ki nle mo pe apa re ka mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Wednesday 23/10/57 T.H.M.S ELO Previous334 · ILE Herrammar ILE HerrammarNext 336 · Ihinrere-Agbelebu