No. 336Ihinrere-AgbelebuLyrics1Ihinrere-Agbelebu Ihinrere-tologo Hossah iye2Mimo mimo Eli-Eli (2ce) Lorin Awon Serafu Lori Oke Soin3C/S Church of Nigeria (2ce) Lati owo Elisha Lene Mu pada si Libreville4Orun nyo-ara aiye ejo (2ce) Lene mu ijo Serafu wa gbin si Ile French5Moses gbi ijo Serau si ilu eko (2ce) Lene rin ninu Sama O ngbin Ajara si Libreville6Ihinrere Agbelebu (2ce) Ihinrere to logo Lene mu pada si Liberville.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo C/S Holy Missionary Journey Libreville Gabon Ap R. V. Omope Zion Previous335 · Kini se Oluwa miNext 337 · Jesu gbe agbelebu fun Lene