No. 343Moti duro lori apataLyrics1Moti duro lori apata Lati ba angeli korin Loke Ugbonla Mo ti duro sori apata Lati ba Angeli korin Mimo o mimo o mimo o2Mo ti je akara ifihan Mo mu ninu ago Kristi Loke Ugbonla Oro Kristi ti mo ngbo O di mana lokan mi Eli o Eli o Eli o3Awosama gbe mi fo Pade awon Serafu Loke Ugbonla Won nfiye gbami mora Won fun mi lebun orin Hu hu hu hu Eli o4Emi gbe lene duro Lori afonifoji oke ugbonla O si nso asotele Lori egungun gbigbe Gbogbo won gba IturaChorusMimo o mimo o mimo o Eledumare o Eli e.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo C & S Previous342 · Pisalemu Olori OrinNext 344 · Olorun mi gbo adura mi