Before you read

No. 344

Olorun mi gbo adura mi

Lyrics

Chorus

Baba dariji mi - Baba sanu fun mi o Baba dariji mi

Chorus

Baba dariji mi - Baba sanu fun mi Baba dariji mi.

Chorus

Okan mi nkun fun ese Baba fo odi ese Kuro ninu okan mi

Chorus

Baba yara gbami-Mase je kin segbe Pleu ese ti mo da.

Chorus

Baba fi ese jimi - Baba sanu fun mi Baba dariji mi o.

Amin

About this hymn

Written by
Prophet Mennary

Orin Mimo ni Friday 26/4/1957 Gbangba loju re Oluwa Tosan torun bakana ni se ijewo ese re ki Olofin to de. The Hammar Romissionally