No. 346Jeki a fi ope fun OluwaLyrics1Jeki a fi ope fun Oluwa Tori omo rere to fifun wa NI ILU ERI2Ogo orun sokale Ewe orun ba alore de Alliluya3Eda ti oju ko ti ri Ni Olorun fifun wa ni ilu ERI Alleluyah4Gbogbo araiye eba mi yo Nipa omo Sioni to de o Alilluyah5Gbogbo Alore orun duro Lati wo bi a o ti se ike ewe to Jeka se ike omode.6Esu ngbogun lori aboyun Awon aboyun si tun di olomo Eje ka yo7Ayo orun sokale Omo Siloh si nba wa gbe o Alleluyah.AminAbout this hymnWritten byProphet Mennary160(b). Orin Mimo ni Thursday Noon Orin Ayo Alore Omo Zion The Harmmar Romisionally Previous345 · E ha ti se ti awon eniaNext 347 · Esin mi lo-Esin mi lo-Enyin alore