No. 347Esin mi lo-Esin mi lo-Enyin aloreLyrics1Esin mi lo-Esin mi lo-Enyin alore E sin mi de oju ona koto Nibiti aja ko le de o Esin mi lo-Esin mi lo-Enyin alore2Ororun fun Ibakase lati wo oju abere / 2 timee Ju fun Oloro lati wo Ijoba o Esin mi lko - Esin mi lo - Eyin alore3Toro loju ona to lo sibi iye Gboro loju ona to lo sibi iparun Gboro ni Oloro nrin o Toro ni Lasaru nrin o Ma sin mi lo-Esin mi lo-Enyin Alore4Esin mi lo-Esin mi lo-Enyin alore. Esin mi de ori ite Baba Nibiti egbe mimo wa o Esin mi lo-Esin lo-Enyin Alore5E fi fun mi-Efi fun mi-Enyin Alore Agbara emi ti Kristi Oluwa Agbara emi awon Aposteli lo o E fi fun mi-E fi fun mi-Enyin Alore.6E ko fun mi-E ko fun mi-Enyin alore Orin mimo ti Dafidi ko Orin mimo ti Odo Aguntan o E ko fun mi-E ko fun mi-Enyin Alore7Eko fun mi-E ko fun mi-Enyin alore Orin mimo ti awon Angeli nko Orin mimo ti awon oke meje nko o Eko fun mi-Eko fun mi-Enyin alore.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday Night 18/5/57 The Hammar Romisionally Previous346 · Jeki a fi ope fun OluwaNext 348 · Ihinrere Ihinrere