No. 353Kristi lo je Oba ododoLyrics1Kristi lo je Oba ododo A! e se loba E se odo aguntan loba Ojoko lori ite to ga A! e se loba.2Aso iguwa re kun Tempili A e se loba Awon agbagba fi ade won lele Eda alaye si nkorin mimo Nwon nse loba.3Pupo awon onigbabo igbani Ti nse loba Nwon mope omo Olorun ni ise Nwon si npe oruko re ni Rabbi Nwon nse o loba.4Gbogbo eya ati orile ede E se loba Gbogbo enyin to ngbo iwe Kristi Je ka tele ohun ta ngbo A! E se loba.5Fi eti orin ti Angeli nko A E se loba Imole irawo su okunkun Ojo ati osupa su okunkun A! idajo de.6Bi nko ba se Krsiti loba A! iya mbe fun mi Baba jo ran emi re simi Baba jeki nle gba o gbo Kin le se o loba.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Tuesday Night 3/7/57 The Harmmar Romissionally Previous352 · Kristi eni isaju ati ikehinNext 354 · Ebe mo mbe Olorun mi