No. 354Ebe mo mbe Olorun miLyrics1Ebe mo mbe Olorun mi Ko fi ogo orun wo mi Ko ko mi ni ilo orun Temi o lo larin ijo Orun ododo yara bo o Le okunkun aiye kuro lodo mi Fun mi ni oro orun so Ti emi o so larin ijo re2Fi emi Alore re wo mi Fi oju adaba wo mi Mu oju mi sa fun ese Yi pada si iran orun Emi iwosan yara bo o Wo inu omo re se ise ogo Kristi je ka ri o Larin ijo onigbagbo3Kristi Oba ipilese Toju ipilese yi Jeki ogo ikehin yi Poju ti isaju lo Gbin igi ododo sairin ijo re Majeki a rahun onje re Fi ona han awon Woli re Ki won le fi ona han wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Friday 5/7/57 The mennah Sainah Previous353 · Kristi lo je Oba ododoNext 355 · Oluwa to fi ase iwosan