No. 36 · Orin AsoteleWo gbogbo egbe Woli to padeLyrics1Wo gbogbo egbe Woli to pade T'awon ti Pisalemu lowo Ngo-ba won yo.2Jehovah to mu emi bale won Ma je ki emi eke bale won Lo won fun Ogo Re.3Gbogbo awon Angeli ti pade Nwon si nforiba fun Olorun Lori ife Re4Ipe Olorun ti odo Angeli wa Lati ko awon Woli jo sibi kan Lati gba agbara Ogo,5Nigbati Kristi Oluwa ti de Gbogbo ahon akololo nsoro Ni ketekete6Kristi jo si wa loju emi La wa lahon lati so oro Re Ni ketekete7Gbogbo enyin Omo Woli to pade E bere Oju ati emi isona Lodo Oluwa.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO Sainary AloreAlbumOdun TuntunRamatu Mennary Ajimuda5 hymnsSimilar hymns119Wo Woli Siloh to ti Judiah sọkalẹ1958 · Orin Asotele188Korin ogo silohOrin Asotele76Ibaṣepe Mose ko wa saiyeOrin Asotele186Ọlọrun yan mi si woliOrin Asotele Previous35 · Alore Ọlọrun SimiroNext 37 · Mo wa sọdọ rẹ loni o, Baba Olore o