No. 366Olugbala gbo ohun miLyrics1Olugbala gbo ohun mi Fi agbara re gba mi Wo gbogbo awon omo oso Ti ngbero ibi simi Nwon nfe ona lati tu ijo ka Nipa asotele eke Agbara mi ko to akoso Kristi mu ijo re pe.2Gbogbo awon omo oso si nbinu Nwon ngbero ohun asan Awon oba won nkese jo Ati awon Woli won Nwon ngbimo si eni ayanfe re Nwon fe ja oku oto re Baba jo suti si won Ki o fi ese ijo mule.3Baba jo fi Oba re je Loke Sioni ERI Jeki a ma soro mimo re Jo se wa lomo re Jeki orile ede pupo Le wa si ijosin re Fun Woli re lopa irin Kofi se akoso Ijo4Gbo ohun mi gbati mo ba pe Olorun Olododo Gba Ijo re lowo ijo eke Fi oju rere fun wa Jeki apo ni iye ati ore ofe Jeki a kun ile aiye Mo fi ohun mi kigbe si o Gbo ebe mi eleda mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Monday 22/7/57 Awon Oba aiye nkese jo pe ki afa ide won ja. Tune: Ose rere T. H. S. H.. Previous365 · Siloh mbo lati mu okunkun aiye kuroNext 367 · Wo bi awon Angeli Ayanfe