No. 367Wo bi awon Angeli AyanfeLyrics1Wo bi awon Angeli Ayanfe Ti nkorin ododo Siloh Nwon si nra bi Adaba Labe Olofin Omo Siloh A! ayo orun.2Wo bi awon Angeli ainiye Ti nkorin ogo ni ilu ERI Nwon nkorin mo oro Olorun Nwon ta apa won di iko esu - Aleluyah.3Mimo Mimo ni Siloh Ki ba awon alaise ododo gbe Eje ki a ko eke sile Ka le ni ipin ninu ewa orun A! ayo Alore.4Wo bi ojo tin bi Ogo Ogo si nbi awosanma Ojo de ojo soro Orun de orun fi imo han A! ewa Orun.5'Gbati mori iran orun Eran ara mi di oku iyepe Emi mi ba Angeli nfo O ko eran ara mi sile Elohemih o Elo.6Wo bi Adaba mary alau Ti nra baba loke Sioni Ogo aiye fo lokan mi Oju mi si nwo ona Siloh A! ayo orun.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Tuesday 23/7/57 Oluwa mu awosanma buburu aiye kuro loju awon iranse re osi mu oju won temo iran orun. Tune: Jesu ye titi aiye. T.H.S.H. Previous366 · Olugbala gbo ohun miNext 368 · Oro Olorun ti oke wa o Aliluya