No. 369Emase fi imele se ise ti OlorunLyrics1Emase fi imele se ise ti Olorun Emase fi imele se ise Imotin para ko ye Nasiri Oluwa o Emase fi imele se ise.2Ise pupo lo wa logba Oluwa Alagbase ko to E yara lo se ise ki e le je alagbase Emase fi imele se ise3Ise ibinu ko ye Nasiri Oluwa Emase fi ibinu se ise Ki Omo Olorun binu ki orun ma wo ba Eje iko alafia ododo .4Baba dariji lati pa ara Ninefe run Ara Ninefe be baba Baba darijji won o fun won ni ibere rere Ibinu Baba pari si won.5Olorun ran Angeli ki o lo pa aiye run Oke meje be Baba o 'Gbana ni Baba ran Angeli miran si Angeli Ologun 'Pe ko mase pa aiye lara.6Okun ki ja ki o ma tu o nipa oro Oluwa Beni ibinu Baba tiri Ategun ki fe ki o ma tutu o ara mi Eyi se apere ibinu Ologbon.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Thursday Night 25/7/57 Orin mimo ikede iko alafia T. H. S. H. Previous368 · Oro Olorun ti oke wa o AliluyaNext 370 · Awamaridi ni ise Oluwa