No. 368
Oro Olorun ti oke wa o Aliluya
Lyrics
Chorus
Gbogbo enyin omo ERI Eje ka fi ara bale Ki awon angeli Olorun le ma ba wa pe Ki ale ti ipa won di agbara.

Amin
About this hymn
- Written by
- Prophet Mennary
Orin Mimo ni Tuesday Tune: Eba mi gbe oro Kristi ro T. H. S. ORUN