No. 371Jesu ta bi ni ajodun ile eroLyrics1Jesu ta bi ni ajodun ile ero O fi ara han Mose ki a to bi o Iyin ni fun O.2Jesu ara Bethlehem kekere Oran emi re wa aiye ki a to bio Iyin ni fun O.3Jesu iwo to pade Abrahamu To fun o ni idameta ini re Ogo ni fun O.4Jesu mimo Omo alade Davidi O fara han Isaiah ki a to bi o Iyin ni fun O.5Jesu onidajo aye ati oku O fi ara han Semeon ki a to bi o Ogo ni fun O.6Iwo odo aguntan gbogbo ile Davidi Gbo bi awon omo re ti nkorin iyin si O Iyin ni fun O7Jesu to ku loke kalfari O fi ara han Aposteli lehin iku re Ogo ni fun O.8Jesu to soro edidi si Olorun Ti ara nsan ti oku mimo si ji dide Ogo ni fun O.9Jesu to ku to jinde lojo keta To gun oke lo si ori ite Baba re Iyin ni fun O.10Jesu to wa lehin igun oke re orun To se ileri emi fun awon Aposteli Iyin ni fun O.11Jesu to ran emi iriran si John To si mu ki Angeli re ma ba soro Ogo ni fun O.12Jesu mimo awa omo ERI mbe O Fun wa lemi iriran to fun awon Aposteli. Ka le fin Iyin ni fun OAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Friday Evening 26/7/57 Tune: Gbo okan mi bi Angeli ti nkorin T.H.S.H Previous370 · Awamaridi ni ise OluwaNext 372 · Jesu Oba igbala - Jesu Oba Iye