No. 372Jesu Oba igbala - Jesu Oba IyeLyrics1Jesu Oba igbala - Jesu Oba Iye Jesu Oba iye - Wo wa o2Wo awon omo re - To wo o Tempili re Jesu olori ijo - Wo wa o3Olorun Elijah - Olorun Mose Olorun agbaiye gba wa o.4Wo gbogbo omo re - otos elese Baba fo odi ese lokan wa.5Bukun wa ni ile - Bukun wa lona Fi oju rere re wo wa o.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Wednesday 31st July 1957 T. H. S. H Previous371 · Jesu ta bi ni ajodun ile eroNext 373 · Kilohun to se o - lona igbala ti mo nrin o