No. 376Lati ori oke ERI ZIONLyrics1Lati ori oke ERI ZION Nibe loro ofin ti wa Awon omo eke nfara won gba Nwon mope oro yio riri won Ete arawon ni won nlepa Nwon ko ba Apata je2Apata pipe ni Kristi Ti nse Olori ijo wa Kristi wa ku on situn ye O joko lori ite Owo re lati ri emi gba Kise owo olori aiye3Gbati Kristi ti gbin igi iye Soke ERI ZION Lawon omo oso ba nko ra jo Lati ya eko Kristi Baba to gba Mose la Jo gba awa omo re la4Olori oso omodo aje Nwon si nsa ara won jo Kise lati sin Olorun Ni kikora jo na Nwon nse Kristi Olori ijo Nwon ko fe mo eko re5Aje nsotele oso nwasu Nwon hale gba Kristi gbo? Nwon yio ma hale ainidi Ninu isin aini ERI Nwon nsope Olori aiye ni won mo Nwon ko mo Kristi iye6Mose sope eniti o ko Kristi Act. 3:22 Yio ku laisi atunse Wo bi awon omuti ti ngan Kristi Ti nse apata wa Apata to bi won ni won ko mo Abukun won nise.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Monday 5/8/57 T.H.S.H Previous375 · Ibasepe Mose ko wa saiyeNext 377 · Rosually Rosually Rosually