No. 375Ibasepe Mose ko wa saiyeLyrics1Ibasepe Mose ko wa saiye Ti Olorun ko lo Woli kankan Nibo lawon Woli iwoyi Yio ti ri iwe ka2Nigbati Olorun lo Joshua O si ko loro ti yio so Bi Olorun ba lo Woli kan Yio fun loro so3Tani ninu awon Woli Olorun Ti ngbe iwe fi lo ma wasu Biko se ki won jeri si Oro iwe mimo4Peter jeri si oro Davidi O tun jeri si oro Joel Emi Kristi lo nko de ibe Kise iwe lo ka5Kristi jeri si oro Isaiah Pe gbigbo won yio gbo oro on Sugbon oye ko ni ye won Beni Oluwa nso6Elemi to nso ede Ati ariran to nsotele Nibo ni asotele yin wa A! ainu se mi.7Gbogbo Woli ti Olorun ti nlo Won kise alagbase fun eda mo Awon woli aiye iwoyi Je alagbase eda8Ebe mo mbe Olorun mi Ko ba mi toju ebun to fun mi Bi aiye tile ko ERI re Sa malo mi si.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Sunday Evening 4/8/57 Orin Oro Sori Woli Eke T. H. S. A Previous374 · Eniti o se taiyeNext 376 · Lati ori oke ERI ZION