No. 386Kristi OLugbala wo miLyrics1Kristi OLugbala wo mi Are mu mi ara ni mi o Ota aisododo de simi Iwo nikan lo le gba mi o2Kiniun nke rara lode Paramole nbu ni ile wa Nwon nyi oju won si wa si ibi Nwon nke haha lati gbe wa mi.3Iwo yio ha da iri re duro? Lori Woli Hasiri re Iwo yio ha da oro re duro Lenu Woli Mennah ALore4Ebe mo mbe Olorun mi Mase gba iran re lodo mi Mase da iri ro lori mi Fun mi lahon akoni ododo5Kristi iwo lo fon ipe simi To pe mi kuro ninu aiye Aiye ngan mi nko ka si Mo nwo ona fun igbala odo re.6Bi iponju esu ba de ba mi Bi nkepe o bi e ko ba gbo Esu yio ma yo ayo ayole Yio si fi agbara ba mi ja7Baba mu iri re ba le mi Fi awosama re se aso mi Je ki ojo emi ro sori mi Ki nle sin o de opin emi mi8Siloh ti Woli nsoro re Je ki nle fi oju mi ri Jeki o le se ise loju mi Ka mi mo awon ti yio ba rin.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Thursday 19/9/57 Previous385 · Igbagbo dara lopolopoNext 387 · Adaba Eri mi o - Nibo lo re o?