No. 39Jesu omo Baba temi di owo reLyrics1Jesu omo Baba temi di owo re Majeki emi sina ninu Ogbon re Majeki are mu mi lona ajo yi2Wo gbogbo igbi aiye ti nyi mi kiri O nbu niwaju mi ati lehin mi Majeki igbi aiye le bori mi3Igbi omi pupo lo wa lona yi Awon alagbara nsanre yi mi ka Jesu omo Baba se ona mi ni ire4Nitori oro re aiye nkegan mi Mo si di ajoji si ara ilu mi Olorun Elijah temi dowo re5Oke pupo lo wa, ti ki se tire Igi pupo lo hu ti iwo ko gbin Oye pupo lo wati iwo ko yan6Jesu Omo Baba wo oke won yi Ti nwon si ngberaga ninu imo esu. Olorun Elisha wa ke won lule7Gbogbo ero ara ti araiye nro Gbogbo idajo eke ti ara aiye nse Jesu Omo Baba ko ma fi owo siAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1964TuneOLODUMARE GBO OHUN EBE MIAlbumOdun TuntunRamatu Mennary Ajimuda5 hymnsSimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion6Funfun gbo, lọrọ Ọlọrun1968 · Orin Iyin ati Ọpẹ7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ Previous38 · Olorun to da ojo oniNext 40 · Lodun ti Usia oba ku