No. 6 · Orin Iyin ati ỌpẹFunfun gbo, lọrọ ỌlọrunLyrics1Funfun gbo, lọrọ Ọlọrun Logo logo ni işẹ rẹ Nitorina lọkan mi şe nfẹ.2Awọn irawọ ngbarajọ Ogo Oşupa ntẹle wọn Nwọn si fori balẹ f' Ọlọrun.3Awọn Adaba nsin Ọlọrun Awọn Angeli nsin Ọlọrun Wa ọrẹ mi, jẹka sin Ọlọrun.4Wo awọn mimọ lori itẹ Wọn we Lawani lori Nwọn si foribalẹ fun Ọlọrun.5Baba gbete mi sọrọ Baba foju mi riran Majẹ ki adun aiye mu mi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryYear1968ORIN MIMỌWritten on 23 August 1968.Similar hymns112Oju Kristi ni oju Adaba miOrin Iyin ati Ọpẹ34Jẹki a tẹriba fun OluwaOrin Iyin ati Ọpẹ101Gbọ, gbọ, gbọ orin JubbiliOrin Iyin ati Ọpẹ144Halleluyah ayo mi kunOrin Iyin ati Ọpẹ Previous5 · Gbo orin didun kan ti mo gboNext 7 · Afurugbin oro Olorun