No. 409Emi ntenumo - Emi ntenumoLyrics1Emi ntenumo - Emi ntenumo Pe awon miran yio kuro ninu igbagbo o Emi ntenumo2Fi iyin fun Oluwa - Fi iyin fun Oluwa Bi iwo ban se Omo bibi Oluwa o Fi iyin fun Oluwa3Ogo Olorun farahan - Esu ngberaga On fe fi igberaga re ba ogo Olorun je o. Baba ba wa le lo4Holy Holy ni ida Oluwa nke o Je ki gbogbo elese safi ara pamo o Ki won se ijewo won5Adaba Mennary ran loke yi o Gbogbo onigbagbo sa fi ara bale o Baba yio toju wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Friday 30/11/57 The Hermmar Sainary ALore Previous408 · Sunmo Kristi gbe agbelebuNext 410 · Mase gbekele enia ninu aisan re