No. 410Mase gbekele enia ninu aisan reLyrics1Mase gbekele enia ninu aisan re Sa gbadura si Oluwa Yio si gba o la2Bi aisan de si alaisododo Inu aiye yio baje Bi olododo sa ti nku lo Inu araiye yio dun3Mase gbekele enia - Ju Olorun lo Baba to wo Hesikia san Yio si wo o san4Moses gba Mariamu la Lowo arun ete re 'Gbati aisan ba Moses ja Mariamu ko le gbala5Elisha wo Namani san Ninu ete re Nigba ojo aisan Elisha Namani ko le gba la6Kristi gba pupo alaisan O la oju afoju 'Gbati ojo iku re de Tani lo se ike re7Oluwa to ji oku dide To gba elese la Ko si oku to tun kainu re Elese fi nse esin8Jesu to fi emi re lele Tori awon ore re 'Gbati iku tire de ba Ko si ore to le gbala9Gbo eko mi omo ogun Oluwa Sa tuju re ka Sa fi fe ba gbogbo enia gbe Ngo dide fun igbala re10Bi o tile ni ife gbogbo aiye To lebun iwosan 'Gbati aisan tire yio ba o Kole si eniti yio se aijo re11Lo ranti iwe Moses Lo ka iwe Elisha Ranti iwe Kristi Olugbala Ki o ko eko ninu re.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday 7/12/57 The Hermmar Sainary Alore Dide kuro ninu akete aisan re Mo segun aisan fun o. Previous409 · Emi ntenumo - Emi ntenumoNext 411 · Olorun wo pupo awon enia re