
No. 411
Olorun wo pupo awon enia re
Lyrics
Chorus
Nwon ko bu ola fun ogo Olorun Nwon ngbe ogo aiye ro
Chorus
Nwon ko bu ola etc.
Chorus
Ete arawon ni won nlepa Ni ijoba Jehovah
Chorus
To nse eleda won.
Chorus
Olorun Elijah mo mbe o Maje ki esu gba ade mi
Amin
About this hymn
- Written by
- Prophet Mennary
Orin Mimo ni Friday 13/12/57 P. A. W. D The Hermmar Sainary Alore Tune: Gbogbo enyin iran Isreal