No. 415Odun gbo - Odun peLyrics1Odun gbo - Odun pe Esu gbe arakere itanje re de O nrin kiri lori ile gbigbe Onwa eniti yio se omolehin on2Apejo mimo pupo lo wa Tawon enia mimo nse lakoko Odun Angeli pupo ni yio pade nibe Onigbagbo sora nibe3Odun to ipe pupo yio jade Ipe ibi yio so ipe rere yio so Gbogbo Woli ekiyesi ara Ki e ma ba gba ipe esu fon4Odun pe esu yio se asehan Yio si tu ohun dun pupo jade Lati mu awon onigbagbo sina Kuro ninu igbagbo won.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Sunday 15/12/57 Holy Pretend Mennah 7% T. H. S. A Previous414 · Rohin mi fun Olorun o MennahNext 416 · Wo duru olokuna ainiye