No. 416Wo duru olokuna ainiyeLyrics1Wo duru olokuna ainiye Ti Olorun fifun awon enia re Lati korin iyin ope si Oluwa2Wo awon Adaba Mennary Olorun To nra loke ile Herrammar Nipa orin ti awon Angeli nko Wa ni ile Herrammar3Wo agbala mimo to sokale To lele ni igun merin Nibe ni awon Angeli nfon Ipe orin simi4Wo awosanma to sokale To nfunfun gbo bi iri sno Ninu re ni Angeli nta oku Orin simi5Enyin ara ilu Eri eje kayo Tori ise ogo orin mimo Ti Olorun fifun wa lati ma sin on6Iwo Adaba mimo ti Olorun nran Lati fun mi lorin eko Mase fi mi sile fun esu lo mo7Iwo emi Olorun to nba mi lo Mase fi mi sile - Mase jeki nseke Ki nto pari ire ije mi8Owo iri mimo to sokale Ta pada di ogbon ati eko Baba mase gba oro ogbon re lokan mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Monday Noon 16/12/57 Holy Pretend Mennah The Hermmar Sainary Alore Previous415 · Odun gbo - Odun peNext 417 · Iri ibukun lemi ntoro