No. 422A o layo bi awon alore torunLyrics1A o layo bi awon alore torun Nitori emi Kristi sokale nba wa gbe Ayo o ire de o ayo ire de.2'Gbawo l'emi yio baa won Alore dogba? To nkorin ayo ni ile Herrammar Ayo o ire de o Ayo o ire de3A o layo bi awon Alore t'orun Nitori omo Siloh sokale nba wa gbe Ayo o ire de o Ayo o ire de oAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Friday Evening Service 2/5/58 Levi Bible G.J Previous421 · Wiri wiri Wiri wiriNext 423 · Iwo itasan to tan