No. 423Iwo itasan to tanLyrics1Iwo itasan to tan Ti ojo ko le pa Iwo iri to nse Ti orun ko le gbe o Wo inu okan mi2Iwo oju elewa Ti ibaje aiye ba Bi ibaje ti ba o to Iwo ko baje o Sa wo oju mi3Iwo oju to nriran Ni kedere ni gboro Aiye tu ito si oju na Sibe ko dipa o E wa Oluwa ni4Iwo apa elewa T'araiye fi iso kan Bi won ti ba o je to Iwo ko baje o Apa mimo5Iwo ewa taiye nbaje Ti ki idibaje Olorun iwo nikan Lo ni ayo pipe o Sa wo inu mi6Iwo ti lewa pupo Ju olufe mi Gbogbo eya ara re Ni iwo fi wu mi - o Oluso mi7Iwo orun to nran Ti ojo ko le pa Iwo ojo to nro Ti ina ko le gbe Sa wo inu mi8Adaba mi Iwo sa ti lewa Ko si ebu kan Taiye le yo lara re - o Olufe mi9Oluwa mi Bi ewa re ti po to ni Sibe awon omo enia Ko feran re - o A Olufe mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Tuesday 29/7/58 Centre Hermmars Rulers The Hermmar Sainarially Alore Sensity Previous422 · A o layo bi awon alore torunNext 424 · Like a river glorioua