No. 435Gbo, gbo, gbo Orin JubilleeLyrics1Gbo, gbo, gbo Orin Jubillee Orin iyin eleda wa Gbo bi iro re tin dun jakejado Ara aiye e wa Ka yin Olorun2Wo bi awon egbe orun ti nda wole Nwon nkorin ti Jubilee Gbo bi iro re tin dun bi iro agogo Ara aiye e wa Ka si Olorun3Yin, yin, yin Olorun Eleda re To fun o lebun ini To fi omo re rubo fun o Ki o le gba o Lowo ese4Gbogbo enyin idile ati iran E korin ti Jubilee E soro odun ti jubilee fun gbogbo aiye Ara aiye e wa Ka ko orin iyin na.5Gbogbo awon onigbagbo igbani Ti nkorin ti Jubilee Nwon nkorin na pelu okan mimo Nwon ko ko fun Afe aiye6Gbogbo enyin Orile ede aiye To gbo Orin ti Jubilee E yi ara nyin kan ni idile idile Ara aiye e wa Ka yin Olorun.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Gest Interration Mana The Hermman Sainary Alore Previous434 · Gbogbo eyin Omo oke EriNext 436 · Romennah Romennah Sadau lau