No. 436Romennah Romennah Sadau lauLyrics1Romennah Romennah Sadau lau (2ce) Olorun, Olorun, Olorun wo mi2Oke giga, giga, nga soke Bawo ni petele yio ti ri? Olorun, Olorun, Olorun wo mi3Eiye Omufo ati Adaba nfo Bawo ni alapandede yio ti ri Olorun, Olorun, Olorun wo mi4Igi elewa ti Olorun gbin On lesu nfo epo sori re Olorun, Olorun, Olorun wo mi5Wo bi itana lili ti nku nlo Ti osusu si ngba ilu kan Olorun, Olorun, Olorun wo mi6Romission ati ALore pade Adaba Menarry da won ro Eri Alo - Eri Alo- Eri Alo, wo mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous435 · Gbo, gbo, gbo Orin JubilleeNext 437 · Gbati mo ba ti ilu eri kuro