No. 443Alore Mininah Mennah Messiah eri ZionLyrics1Alore Mininah Mennah Messiah eri Zion Yara fun lomo bi Jowo fun lomo bi Ki nle ye se iye meji2Awon omo Ologo ti mori Lori oke eri Zion Bi nko ba bi ninu won Emi yio kanu pupo3Baba jo fun mi lebu mi meta Ti esu fi nri oro so si mi Owo-omo Ati agbara emi4Mo nfi emi nwa ona ibimo Mo pade omo woli aiye kan O bere owo lowo mi O bere candle lowo mi Pe bi mba fun on ngo ri omo bi5Gbana lemi Olorun ba le mi Pe kin lo fi ara bale Pe kin fi okan bale Pe a ki nfi owo Bere omo Ologo6Enyin alore Te nkorin simi Ati Olorun ti mo nsin Mo nbere ebu ibimo Ati agbara emi lowo nyin Mo be yin ki e fifun mi7Agbara emi meji ti Olorun Angeli ti o to Osupa ati irawo Mo wole ruburubu labe yin Ati labe Olorun Pe ki e fun mi lomo bi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous442 · Ha Olorun Oba OnidajoNext 444 · Mu egan mi kuro Oluwa