No. 444Mu egan mi kuro OluwaLyrics1Mu egan mi kuro Oluwa (2ce) Mo gbe oju mi soke si O Mo tewo mi meji sodo Re Mu egan mi kuro o2Fi iran fun mi ri o Oluwa Fi ede fun mi so o Oluwa Nko lagbara lati da iran so Mu egan mi kuro o.3Fi ogbon Olorun fun mi o Oluwa (2ce) Fi ebun Emi Re fun mi Mase ro ti asedede mi Fi oju anu re wo mi o4Fun mi lagbara asotele (2ce) Fun mi lagbara iran Ogo Re Kin le fi mu eke ati efe kuro Mu aipe mi kuro o5Mu egan mi kuro Olorun (2ce) Jeki erin kun ereke mi Mo bere omo ati agbara Emi Fi fun mi ni josin Re o.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous443 · Alore Mininah Mennah Messiah eri ZionNext 445 · Oju Olorun lo yi aiye ka