No. 445Oju Olorun lo yi aiye kaLyrics1Oju Olorun lo yi aiye ka O wa nihin o wa lohun Ko si ohun ti a se nikoko Ti oju Olorun ko ri2Ojo kan soso lo nyo lorun O nmole yi gbogbo aiye ka Osupa kan lo nran lorun O wa nihiin o wa lohun3Olorun to nso ibi di ire Mu ise buburu mi kuro Jeki eje Kristi omo Re Le fo gbogbo ese nu4Wo bi esu ti nba Olorun jiyan To npin aiye sona meta O nfe fun Olorun lapakan Ki on le ko apa meji iyoku5Awamaridi ni Olorun To yi Paul ni iye pada Kuro ninu isin awon Ju To pe mo ijo Aposteli6Baba mi ko ni gba fun esu Lati mu awon ayanfe re Sugbon yio fi awon enia kan sile Lati lo si ina ebi Orun.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous444 · Mu egan mi kuro OluwaNext 446 · Gest gesting Gest Mannar