No. 459Oju kan mbe ti ki suLyrics1Oju kan mbe ti ki su Nigbati oju gbogbo ba sun Eti kan mbe ti ki ise Nigbati eti gbogbo ba se Oju na nwo ona Olorun Eti na sin gboro Olorun2Nigbati oju gbogbo ba sun Oju emi Olorun ki isun Nigbati eti gbogbo ba se Eti emi Olorun ki ise Baba fun mi loju emi Ki nle fi ma wo ona emi re3Bi aisan mbo oju ara ki mo Bi o dele tan oju ara yio ri Bi iku ba mbo eti aiye ki gbo Bi o pa nitan eti aiye yio gbo Baba fi oju emi Re fun mi Ki nle je ariana ati Oluso.4Nigbati oju ti ara ba nsun Ko ri iwaju ko si ri ehin Nigbati eti ara ba se Ko gbo oro Orun ko gbo laiye Oju emi yio ma se ise Ohun iriri ati ohun ti mbo.5Nigbati a ba wa ninu orun Ti awon ota wa ba yi wa ka Oju emi wa yio ma ri won Emi Kristi yio mu wa yo Oju emi ati eti emi Lo gba wa lowo ota wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous458 · A de Oba eri lereNext 460 · Gbati mo ngboro egan