No. 460Gbati mo ngboro eganLyrics1Gbati mo ngboro egan Ti awon eda Olorun Nsosi Olorun to mo ori won Enu mi na lati soro o Sainary alore nkorin si mi.2Emi igbala ara mi Simi ninu ireti O si fun mi ni ago omi titu Wipe ki nfi bo oju pe ki nfi fo enu Ki nfi okan si ona Olorun3Wo bi awon Onigbagbo Ti nwasu fun Keferi Lati wa gba Olorun gbo Beni awon keferi si nsoro isata Lati yi olododo pada4Koto iku ti esu wo Okun isubu ti on nta Baba maje ki nrin sinu re Jeki okun won ati koto na Lefi awon na je lodun yi.5Wo Osupa Ologo aileku Ti Olorun gbe dide Fun igbala gbogbo omo eni Beni awon omo enia siko Ogo aiku Aiye feran eke ju otito lo6Oko igbala Oluwa Ni igbin aiye nbaja lojojo Nwon si nfe te Oko Ogo rin A! iro ni aki igbo iro iku Si Olorun eleda mi7Wo Osupa Ologo To duro fun igbala araiye lode orun Ti awon igbimo aiye ngbimo si Awon araiye; si nfe si nipo Olorun ki isipo pada.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous459 · Oju kan mbe ti ki suNext 461 · Oluwa fi awosanma didan