No. 462Awon ara igbani to nfi otito sin OluwaLyrics1Awon ara igbani to nfi otito sin Oluwa Nwon fi aiye sile won di ijo Orun Nwon ko beru awon igbi aiye Nwon fi igboya nsoro Olorun2Lojojumo ni esu ndena won Araiye muwon kan aba mo lese Bi aiye tin se inubinu si won to Nwon se omo araiye ni ibi3Idanwo pupo lo wa ninu Igbagbo Idena po ninu ihinrere Gbati enyin ba mbo sinu idanwo E fi suru re idanwo koja4Igba kuna fun mi lati so Ti Stephen eleri oloto Ti awon Ju so ni okuta pa Olorun nikan lo kegbe si.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous461 · Oluwa fi awosanma didanNext 463 · Oke yi, Oke yi Oke yi