No. 461Oluwa fi awosanma didanLyrics1Oluwa fi awosanma didan Si oju awon ayanfe re Lati mo Ogo orun yato Si Ogo aiye.2Oluwa fi ihinrere Mimo Sinu awon ojise Re Lati se asaro oro Olorun Ju taiye lo.3Ododo ni ise Olodumare Ko si eke ninu re Ayanfe Olorun to ba nseke Yio si segbe4Bi eni kan joko soke tempili To nseke si Olorun Oluwa Olorun yio mu kuro Ni oke mimo,5Eke nke ni kuro loke Olorun Otito ngbe ni ro Ihinrere Olorun kii idagba Pelu eke.6Olododo to joko sibi ikoko Ni ile OLuwa Olorun On yio si ri idalare gba Ju awon ijoye to nseke7Iwo awosanma didan Ti Oluwa Olorun Fi si oju awon Ojise Re Lati ma riran Ogo Olorun8Eni to ba ti ri awosanma didan Ki fi iyesi oro aiye Ki Ogo awosanma Olorun Ma ba fo lo.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous460 · Gbati mo ngboro eganNext 462 · Awon ara igbani to nfi otito sin Oluwa