No. 472Kristi ni Olori ijo yiLyrics1Kristi ni Olori ijo yi Wo bi osi mi ti po to laiye Wo bi ise mi ti po to laiye Wo bi egan mi ti po to laiye Baba jo gbaro fun mi2Bi afoju lemi omodo re To nwa oju ona ti ko ri Baba je ki nle ri ona re o (2c) Silekun re fun mi.3Bosepe Oluwa ko je temi Awon ota mi iba ti mi mi Gba mi Olorun Alore o(2ce) Mase fi mi sile nikan.4Ise mi po pupo laiye esu yi Olorun nikan lole gba mi la Mase jeki emi 1e sina o (2ce) Ninu Ijoba re.5Mimo ni ori Oke Olorun Elese kole gun oke na Baba jo nu ese mi nu kuro Ki nbale wo ile re.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous471 · Awa ko lesan ti awa yio gba lowo ara waNext 473 · Mokandilogorun dubule je