No. 473Mokandilogorun dubule jeLyrics1Mokandilogorun dubule je Nwon nreti (3 times) Ipe ayo won Lodo Olorun Onidajo won.2E ku iroju enyin arakunrin Ti e duro (3times) Ti e nreti ileri Igbagbo Ti e nyin ti gba alaiye3Wo awon to ni igbagbo pipe laiye Nwon wo aso funfun (3 times) Labe edidi Oga Ogo Nwon npe Oluwa pe se idajo wa4Awon Aposteli ti Oluwa yan Nwon ha duro sibe (3 times) Ogo Oluwa gbe won re ibe koja? Nwon gunwa pelu Kristi5Wo iranse Olorun to wa labe pepe To nte duru (3 times) Olokun Orin ayo To ngbo ni paradise6Orin duru na mo ngbo nihin Ni mo nko (3 times) Nipa emi Olorun Kole mu mi de eti bebe Ogo7Awon Woli Olododo to ti sun Nwon ha duro (3 times) Leba pepe edidi Nwon ko si nibe won ti lo Sorun8Aiye yi kise ti wa Bi o ba pe (3times) Awa na yio sun Bi a se rere a o duro saba pepe Ogo9Nje eni ibi hale ri pepe na lo Iro ni (3times) Inu Okunkun biribiri Lawon eni ibi yio joko si.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous472 · Kristi ni Olori ijo yiNext 474 · Mofi Okan ati ara mi fun Olorun