No. 478Gbo Orin Iyin OlorunLyrics1Gbo Orin Iyin Olorun Ti nti inu Harpu wa Harpu olohun orin adun Lo korin orun fun mi.2Wo bi Igbin Orin ti nyi Ti nwo inu okan mi Orin harpu nwo eti mi Imo orun ngbe ete mi3Gbawo ni emi o ti Ago ara kuro Temi yio pada si ilu emi? Ni ilu isinmi ailopin.4Herpu orin ayo ajinde Duru olokun Wilo Baba mase jeki nsi okan Ninu orin Alore Re5Gbawo ni ngo ri O Iwo herpu ayo Nigbawo ni emi - ri O? Duru olokun aiku6Duru olokun ainiye Herpu ohun elo Orun Olorun jeki nle ni Lati ma korin Re7Gbo bi egbe Orun ti nkorin pe Yiye lo ye Kiristi Gbe iku mi ni Ijoba Re Alleluya8Gbo orin ayo ajinde Tawon asegun iku nko Nwon nkorin ayo bayi pe A gbe iku mi ni isegun.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous477 · Gbogbo enyin ti e ngbara yin joNext 479 · Lati gbe Oluwa ga ni mo se wo tempili