No. 479Lati gbe Oluwa ga ni mo se wo tempiliLyrics1Lati gbe Oluwa ga ni mo se wo tempili Oluwa mi jo fi ara han mi.2Nko wo tempili lati seke si Olorun Olorun jo fi ara han mi.3Lati ri Oluwa ni mo se wole adura Olorun mi jo fi ara han mi.4Lati sin Oluwa ni mo wole adura fun Olorun mi jo fi ara han mi.5Wo bi enia ti mba ara won ja Olorun mi jo fi ara han mi.6Ofin Re pupo ni esu ti mu kuro Olorun mi jo fi ara han mi.7Eje Re iyebiye lo le we ese mi nu Olorun mi jo fi ara re han8Emi gbekele Olorun Olododo mi Ma je ki esu le si mi nipo.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous478 · Gbo Orin Iyin OlorunNext 480 · Eke ti ja mi pupo o, Oluwa mi