No. 480Eke ti ja mi pupo o, Oluwa miLyrics1Eke ti ja mi pupo o, Oluwa mi Bi mo rin sihin mo ri eke Bi mo rin sohun mo ri eke Eke ti ja mi pupo Oluwa mi.2Lorun nikan lemi ti ngbo Oro otito Bi Otito Orun fi mi sile Nibo ni ngo ti gbo Otito Maje ki Otito fi mi sile Oluwa mi.3Iro iro nro lori ara won lode aiye, Okun ese nde ara won Nwon si tun ntura won sile Ko si ilu Otito kan laiye Oluwa mi,.4Emi hale gbe ara ese Wole Ogo Re Ite ese ki iba o gbe po Eke ko le wo Ijoba Re Baba jo ja eke kuro lokun ete mi.5Bi otito orun ti nso mi lo lode aiye Beni esu nran eke si mi Beni esu nran ese si mi Jo fi Otito re ja mi gba lowo esu.6Wo bi iri Olugbala mi Ti nfo mimo. Beni esu si nko erofo ese Lati ba mi lara je Baba jo fi owo iri re fo erofo na.7Wo bi okun ese re ti nde mi Oluwa mi Wo bi iro ati pansaga Ti ngbara won po si mi Nwon fe bi mi sinu iparun Baba gba mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous479 · Lati gbe Oluwa ga ni mo se wo tempiliNext 481 · A! ewa Ogo Oluwa ni mo nreti