No. 482Ewa gboro ifihanLyrics1Ewa gboro ifihan Lenu awon alore E wa gboro ifihan Lenu awon akoni2Wo ojo to nro ninu sanma To nfun to nro to npon Ninu re ni ifihan ewe wa Je ka korin ifihan3Wo awon irawo to han loju sanma Ti ikuku mbo to tun nyo Wo osumare to han labe ite na Nwon nse apere ifihan ewe4Duru ati ilu esa ma iro Ki kimbali ati ipe ma fo Ki gbogbo ijo fi imo sokan Ki awon ewe orun le ba wa pe5Ojise mi farabale Fi ara pamo fun ojo mewa Maje ki aiye mo ibusun re Ki ifihan le fi Eri han o.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous481 · A! ewa Ogo Oluwa ni mo nretiNext 483 · Kristi ti ara lati orun wa