No. 483Kristi ti ara lati orun waLyrics1Kristi ti ara lati orun wa On ni Mary bi ni Bethlehem Nwon ko bi nibi giga iaye Bikose nibuje eran2Kristi na lo je ki a mo Olorun Nipa siso omi di oti waini Nipa lila oju afoju O tun ji oku dide.3Kristi na lara Judia ntele On ni ara Korinti ntele On ni ara Galillee ntele Ara Nasareti ntele4Awon ara Galatia ntele Jesu Awon ara Efesu nsi ntele Iro Kristi mu aiye wariri Pupo won si tele5Bi awon kan ko tele kristi lojo oni. Ete ara won ni won nlepa Awon to ko oro Kristi ni igbani Nwon di eni egbe6Ilu to sin Kristi ni igbani Poju ilu ti ko sin nisisiyi Bi gbogbo aiye ti le je ti Oluwa Ebun abere nifun7Nigbawo l'awa o ri nyin? Enyin ara wa to sin Oluwa Gbawo ni a o ri awon Aposteli. Ti o nsin jesu8Jesu ti o ti odo Olorun wa O yan ijokan sile aiye Oruko ijo na ni ijo Aposteli Pe ki a ma tele.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous482 · Ewa gboro ifihanNext 484 · Bi o se nlo mi lo yi Oluwa