No. 487Alabukun ni fun enyin eweLyrics1Alabukun ni fun enyin ewe To fara mo isin Olorun Ni oro won2Alabukun ni fun enyin ewe To fi ara sile tori Kristi To ngbe agbelebu3Alabukun ni fun enyin ewe To ka ogo aiye si ofo To nfe Kristi4Alabukun ni fun enyin ewe Taiye nse inunibinu si tori mi Ere nyin po lorun.5Alabukun ni fun enyin ewe To sure tete gbe agbelebu Ni oro won.6Alabukun ni fun omodo na Ti ko fi ise Oluwa re se imele Yio gbere lodo oga re.7Alabukun ni ewe na To nru iku Kristi Oluwa kiri Larin awon enia8Enyin ewe to nrin lona Kristi E fi ori ti titi de opin Ere nyin mbe lorun.9Alabukun ni fun enyin ewe To fi ile ati ona sile Tori ihinrere Oluwa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous486 · Enyin ti egbami ihinrereNext 488 · Olorun ni eleda ohun gbogbo