No. 488Olorun ni eleda ohun gbogboLyrics1Olorun ni eleda ohun gbogbo Sokale sa ma gbe arin ijo wa2Olorun Iwo to laju afoju Sokale sa ma gbe arin ijo wa3Olorun iwo leniti o ji oku dide Sokale sa ma gbe arin ijo wa4Iwo leniti o l'aju afoju Sokale sa ma gbe arin ijo wa5Baba to nse iwosan awon alaisan Sokale sa ma gbe arin ijo wa6Baba to ran awon omo re ni ise Sokale sa ma gbe arin ijo waAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous487 · Alabukun ni fun enyin eweNext 489 · Eri Mennah alau