No. 491Mo fi Ope fun o OluwaLyrics1Mo fi Ope fun o Oluwa. To fun mi ni manna onje orun loni Emi si nkorin si O ni tempili loni Nipa agbara manna to fifun mi A! emi dupe A! emi o fi ope fun Olorun2Nipa onje manna ti mo je Fun mi logbon lati kiyesi ara Ki emi ma ba ku bi awon to ku l'aginju Ki emi le ye bi awon to ye Ki nle ma fi ope Ki emi le fi ope fun Olorun.3Pupo l'awon to gbo oro Olorun Ti won si ngba orin Re lenu Alore Nwon ko fiyesi oro otito ti won ngbo Nwon so ara di eri pelu aiye A! inu ina A! inu ina nibugbe won.4Oro Olorun ni iku fun awon arufin O ni iye fun awon ti o gbagbo Gbati Annaniah, ati iyawo re seke Logan ni oro Olorun pa won A! Elo sora A! elo sora enyin o seke.5Olorun to logbon ju gbogbo aiye Jo fi emi irele Re wo mi laso Jo fi ida mimu ti emi ogun fun mi Ko koju mi si ija si esu Ki a le ma yin O Mase jeki esu le wo okan mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous490 · Mininah arialauNext 492 · Iran orun iwo ti leru